YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM-JSS3

YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM-JSS3

by Loise Braina

YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM-JSS3

Week 

(Oṣe)

10 (Kẹwàá)
Date 

(Deeti)

March 11th to 15th, 2024 
Class 

(Kíláàsì)

JSS 3
Subject 

(Isẹ)

YORUBA
Period 

(Akoko)

5th
Duration 

(Iṣẹju)

40 minutes per period 

(Ogoji Iṣẹju)

Resources

(Iwe Itọkasi)

S.Y Adewoyin (New Edition, 2020) Simplified Yoruba L1 for JSS by Corpromutt Publishers.

M.K Gbadamosi (1st Edition, 2008) Asa ati Girama Yoruba by God’s Mercy Publishers

Instructional materials

(Irinṣẹ Ikọni) 

Lilo ate ti o n toka si igbese aroko

Sise amulo apeere aroko ninu iwe S.Y Adewoyin

Lilo fọnran ti o n sapejuwe orisii aroko  

Theme 

(Akọle)

Arokọ
Day 1 

(Ọjọ Kin-in-ni)

11th March 2024 5th period
Topic 

(Akọle)

Aroko
Learning Objectives

(Erongba Idanilekoo) 

Lopin idanilekoo awon akekoo gbodo le:

  1. se ilapa ero lori ore mi
  2. ko aroko ore mi ni akoyege nipa sise amulo igbese aroko kiko. 
Key Vocabulary Words

(Ede Iperi) 

  • Ilapa Ero
  • Ṣiṣẹ-n-tẹle
  • Ifaara
  • Ipin Afọ
  • Isaasun
  • Asọkagba 
Previous Knowledge

(Imọ Atẹyinwa)

Awon akekoo ti imo nipa Aroso 
Content (Akoonu isẹ) Oriki Aroko ati igbese Aroko kiko

Orisii Aroko ti o wa  

Strategies/ Activities (Agbekalẹ) Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.

Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo.

Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo.

Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko.

Classwork

(Iṣẹ ṣiṣe)

  • Daruko igbese Aroko kiko 
  • Daruko orisii Aroko marun-un ti o mo 
Conclusion

(Igunlẹ

Olukọ salaye Ẹkọ lori arokọ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati jiroro lori akọle ti o le ba orisii Arokọ mu.
Assignment 

(Ise Amurele/ Asetilewa)

Ko Aroko onileta si ore re nipa bi ile iwe re se ri.

Read Also: JSS3 French Mock Examination Question- 3rd Term

Day 2

(Ọjọ Keji)

14th March 2024 8th period 
Topic

(Akọle) 

Aroko
Learning Objectives

(Erongba Idanilẹkọọ

Lopin idanilekoo awon akekoo gbodo le:

  1. se ilapa ero lori ore mi
  2. ko aroko ore mi ni akoyege nipa sise amulo igbese aroko kiko. 
Key Vocabulary Words 

(Ede Iperi)

  • Ilapa Ero
  • Ṣiṣẹ-n-tẹle
  • Ifaara
  • Ipin Afọ
  • Isaasun
  • Asọkagba
Previous Knowledge 

(Imọ Atẹyinwa)

Awon akekoo ti ni imo nipa Aroso ati Aroko
Content 

Akoonu Iṣẹ)

Oriki Aroko ati igbese Aroko kiko

Orisii Aroko ti o wa 

Strategies/ Activities 

(Agbekalẹ)

Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.

Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo.

Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo.

Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. 

Classwork

(Iṣẹ ṣiṣe)

Ko igbese Arokọ Onileta 
Conclusion

(Igunlẹ)

Olukọ salaye Ẹkọ lori arokọ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati jiroro lori akọle ti o le ba orisii Arokọ mu. 
Assignment 

(Ise Amurele/ Asetilewa)

Kọ Arokọ Aṣapejuwe lori ILE ẸKỌ rẹ
Weekly quiz  
HODs. Comments and Endorsement

 

AROKỌ 

KINI AROKỌ?

Aroko ni ohun ti a ro lokan lori koko oro kan ti a si ko sile.

IGBESẸ AROKỌ KIKỌ

  1. Akole: akole ni ori oro ti a fe ko aroko le. 

Bi apeere: Ounje ti mo feran julo

  1. Ilapa Ero: iwonyii ni awon koko kekeke ti alaroko ko jo lati fi gbe aroko re kale, ki aroko naa le e wa ni sise-n-tele. Sise Ilapa Ero ni lati dena gbigbe ohun ibere si ipari tabi ohun ipari si aarin.
  2. Ifaara: ohun ni ibere aroko. O gbodo dun, ki o gbe onkawe lokan soke, ki o si toka si akole.
  3. Ipin Afo: ipin afo ni ipin ti koko ero kookan wa. Leta nla ni a fi n bere ipin afo, ti a o si fi ami koma (,) ati ami idanuduro (.) sibi ti o ba ye.
  4. Koko Oro Inu Aroko: koko oro taka si isele inu aroko. Eran die egungun die ni isaasun obe fi n kun. Oro awada, oro efe to pa ni lerin gbodo han ninu aroko wa. Aroko wa ko gbodo gbe hau-hau.
  5. Igunle/Ikadii/Asokagba: ikadii aroko gbodo mo niwon, ki o dun, ki o si fi ero inu eni han.

 

ORISII AROKỌ

  1. Aroko Onileta
  2. Aroko Alalaye 
  3. Aroko Asapejuwe
  4. Aroko Oniroyin
  5. Aroko Asotan
  6. Aroko Alariyanjiyan 
  7. Aroko Ajemo-isipaya

 

LESSON CONTENT FORMAT

 

  • Content should be on MS Word
  • Font style (Comis Sans MS)
  • Font Size (12)

Day 1

  1. State your objectives
  2. Copy and paste your full lesson note

Day 2

  1. State your objectives
  2. Copy and paste your full lesson note

Day 3

  1. State your objectives
  2. Copy and paste your full lesson note

 

Sign up for our newsletter for educational updates

edujects logo

Related Posts

Leave a Comment

error: Content is protected! Contact Admin.