YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM -JSS 2
Week
(Oṣe) |
10 (Kẹwàá) | |
Date
(Deeti) |
March 11th to 15th, 2024 | |
Class
(Kíláàsì) |
JSS 2 | |
Subject
(Isẹ) |
YORUBA | |
Period
(Akoko) |
4th | |
Duration
(Iṣẹju) |
40 minutes per period
(Ogoji Iṣẹju) |
|
Resources
(Iwe Itọkasi) |
S.Y Adewoyin (New Edition, 2020) Simplified Yoruba L1 for JSS by Corpromutt Publishers.
M.K Gbadamosi (1st Edition, 2008) Asa ati Girama Yoruba by God’s Mercy Publishers |
|
Instructional materials
(Irinṣẹ Ikọni) |
Lilo ate ti o n toka si orisii Ere Idaraya nile Yoruba
Lilo fọnran to n safihan awon Ere Idaraya |
|
Theme
(Akọle) |
Ere Idaraya | |
Day 1
(Ọjọ Kin-in-ni) |
11th March 2024 | 4th period |
Topic
(Akọle) |
Ere Idaraya | |
Learning Objectives
(Erongba Idanilekoo) |
Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le:
|
|
Key Vocabulary Words
(Ede Iperi) |
|
|
Previous Knowledge
(Imọ Atẹyinwa) |
Awon akekoo ti imo nipa ere sise | |
Content (Akoonu isẹ) | Oriki Ere Idaraya
Orisii Ere Idaraya |
|
Strategies/ Activities (Agbekalẹ) | Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. |
|
Classwork
(Iṣẹ ṣiṣe) |
Ko orin eremode ti oluko ko | |
Conclusion
(Igunlẹ) |
Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya. | |
Assignment
(Ise Amurele/ Asetilewa) |
Ko orin Ere Idaraya miiran yato si ti oluko |
Day 2
(Ọjọ Keji) |
14th March 2024 | 7th period |
Topic
(Akọle) |
Ere Idaraya | |
Learning Objectives
(Erongba Idanilẹkọọ) |
Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le:
|
|
Key Vocabulary Words
(Ede Iperi) |
|
|
Previous Knowledge
(Imọ Atẹyinwa) |
Awon akekoo ti ni imo nipa orin ere idaraya | |
Content
Akoonu Iṣẹ) |
Oriki Ere Idaraya
Orisii Ere Idaraya |
|
Strategies/ Activities
(Agbekalẹ) |
Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. |
|
Classwork
(Iṣẹ ṣiṣe) |
Ko orin ere idaraya kan ti o mo pelu itumo ni ede Geesi | |
Conclusion
(Igunlẹ) |
Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya. | |
Assignment (Ise Amurele/ Asetilewa) |
Daruko orin ere idaraya meta ki o si salaye igba ati akoko ere naa. | |
Weekly quiz | ||
HODs. Comments and Endorsement |
ERE IDARAYA
Ere idaraya ni ere ti awon omode tabi agbalagba maa n se lati je ki ara won ji pepe. Ni ale ni igba osupa ni awon omode maa n sere ti won idi niyi ti a fi n pe ni ere osupa. Apeere iru ere bee ni bojuboju, ekun meran, ojo n ro, ta lo wa ninu ogba naa abbl.
EKUN MERAN
LILE (CALL) | EGBE (RESPONSE) |
Ekun meran (The leopard stalks the goat) | Mee |
O tori bogbo (It searches the forest) | Mee |
O torun bogba (It searches the bush) | Mee |
O fe mu un (It wants to capture it) | Mee |
Ko ma le ri mu (No you cant capture it) | Mee |
Oju Ekun n pon (The leopard’s eyes are red) | Mee |
Iru Ekun n le (the leopard’s tail stands on end) | Mee |
READ ALSO: JSS2 French Examination Question-3rd Term
OJO N RO
Ojo n ro | It is raining |
Sere ninu ile | Play inside the house |
Ma wo inu ojo | Don’t enter the rain |
Ki aso re | So that your cloth |
Ko ma ba tutu | Would not get wet |
Ki otutu | So that cold |
Ko ma ba mu o | Would not catch you |
TA LO WA NINU OGBA NAA
Ta lo wa ninu ogba naa | Who’s in the garden/yard |
Omo kekere kan ni | One small kid |
Se kin wa wo | Can I come and see her? |
Mo wa wo | No, don’t come and look |
Tele mi kalo | Come here and follow me |