YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM -JSS 2
| Week (Oṣe) | 10 (Kẹwàá) | |
| Date (Deeti) | March 11th to 15th, 2024 | |
| Class (Kíláàsì) | JSS 2 | |
| Subject (Isẹ) | YORUBA | |
| Period (Akoko) | 4th | |
| Duration (Iṣẹju) | 40 minutes per period (Ogoji Iṣẹju) | |
| Resources (Iwe Itọkasi) | S.Y Adewoyin (New Edition, 2020) Simplified Yoruba L1 for JSS by Corpromutt Publishers. M.K Gbadamosi (1st Edition, 2008) Asa ati Girama Yoruba by God’s Mercy Publishers | |
| Instructional materials (Irinṣẹ Ikọni) | Lilo ate ti o n toka si orisii Ere Idaraya nile Yoruba Lilo fọnran to n safihan awon Ere Idaraya | |
| Theme (Akọle) | Ere Idaraya | |
| Day 1 (Ọjọ Kin-in-ni) | 11th March 2024 | 4th period | 
| Topic (Akọle) | Ere Idaraya | |
| Learning Objectives (Erongba Idanilekoo) | Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le: 
 | |
| Key Vocabulary Words (Ede Iperi) | 
 | |
| Previous Knowledge (Imọ Atẹyinwa) | Awon akekoo ti imo nipa ere sise | |
| Content (Akoonu isẹ) | Oriki Ere Idaraya Orisii Ere Idaraya | |
| Strategies/ Activities (Agbekalẹ) | Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. | |
| Classwork (Iṣẹ ṣiṣe) | Ko orin eremode ti oluko ko | |
| Conclusion (Igunlẹ) | Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya. | |
| Assignment (Ise Amurele/ Asetilewa) | Ko orin Ere Idaraya miiran yato si ti oluko | |
| Day 2 (Ọjọ Keji) | 14th March 2024 | 7th period | 
| Topic (Akọle) | Ere Idaraya | |
| Learning Objectives (Erongba Idanilẹkọọ) | Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le: 
 | |
| Key Vocabulary Words (Ede Iperi) | 
 | |
| Previous Knowledge (Imọ Atẹyinwa) | Awon akekoo ti ni imo nipa orin ere idaraya | |
| Content Akoonu Iṣẹ) | Oriki Ere Idaraya Orisii Ere Idaraya | |
| Strategies/ Activities (Agbekalẹ) | Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. | |
| Classwork (Iṣẹ ṣiṣe) | Ko orin ere idaraya kan ti o mo pelu itumo ni ede Geesi | |
| Conclusion (Igunlẹ) | Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya. | |
| Assignment (Ise Amurele/ Asetilewa) | Daruko orin ere idaraya meta ki o si salaye igba ati akoko ere naa. | |
| Weekly quiz | ||
| HODs. Comments and Endorsement | ||
ERE IDARAYA
Ere idaraya ni ere ti awon omode tabi agbalagba maa n se lati je ki ara won ji pepe. Ni ale ni igba osupa ni awon omode maa n sere ti won idi niyi ti a fi n pe ni ere osupa. Apeere iru ere bee ni bojuboju, ekun meran, ojo n ro, ta lo wa ninu ogba naa abbl.
EKUN MERAN
| LILE (CALL) | EGBE (RESPONSE) | 
| Ekun meran (The leopard stalks the goat) | Mee | 
| O tori bogbo (It searches the forest) | Mee | 
| O torun bogba (It searches the bush) | Mee | 
| O fe mu un (It wants to capture it) | Mee | 
| Ko ma le ri mu (No you cant capture it) | Mee | 
| Oju Ekun n pon (The leopard’s eyes are red) | Mee | 
| Iru Ekun n le (the leopard’s tail stands on end) | Mee | 
READ ALSO: JSS2 French Examination Question-3rd Term
OJO N RO
| Ojo n ro | It is raining | 
| Sere ninu ile | Play inside the house | 
| Ma wo inu ojo | Don’t enter the rain | 
| Ki aso re | So that your cloth | 
| Ko ma ba tutu | Would not get wet | 
| Ki otutu | So that cold | 
| Ko ma ba mu o | Would not catch you | 
TA LO WA NINU OGBA NAA
| Ta lo wa ninu ogba naa | Who’s in the garden/yard | 
| Omo kekere kan ni | One small kid | 
| Se kin wa wo | Can I come and see her? | 
| Mo wa wo | No, don’t come and look | 
| Tele mi kalo | Come here and follow me | 
 
									 
					
