YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM-JSS3
Week (Oṣe) |
10 (Kẹwàá) | |
Date
(Deeti) |
March 11th to 15th, 2024 | |
Class (Kíláàsì) |
JSS 3 | |
Subject
(Isẹ) |
YORUBA | |
Period (Akoko) |
5th | |
Duration
(Iṣẹju) |
40 minutes per period (Ogoji Iṣẹju) |
|
Resources
(Iwe Itọkasi) |
S.Y Adewoyin (New Edition, 2020) Simplified Yoruba L1 for JSS by Corpromutt Publishers. M.K Gbadamosi (1st Edition, 2008) Asa ati Girama Yoruba by God’s Mercy Publishers |
|
Instructional materials
(Irinṣẹ Ikọni) |
Lilo ate ti o n toka si igbese aroko Sise amulo apeere aroko ninu iwe S.Y Adewoyin Lilo fọnran ti o n sapejuwe orisii aroko |
|
Theme (Akọle) |
Arokọ | |
Day 1
(Ọjọ Kin-in-ni) |
11th March 2024 | 5th period |
Topic (Akọle) |
Aroko | |
Learning Objectives
(Erongba Idanilekoo) |
Lopin idanilekoo awon akekoo gbodo le:
|
|
Key Vocabulary Words
(Ede Iperi) |
|
|
Previous Knowledge (Imọ Atẹyinwa) |
Awon akekoo ti imo nipa Aroso | |
Content (Akoonu isẹ) | Oriki Aroko ati igbese Aroko kiko
Orisii Aroko ti o wa |
|
Strategies/ Activities (Agbekalẹ) | Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. |
|
Classwork
(Iṣẹ ṣiṣe) |
|
|
Conclusion (Igunlẹ) |
Olukọ salaye Ẹkọ lori arokọ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati jiroro lori akọle ti o le ba orisii Arokọ mu. | |
Assignment
(Ise Amurele/ Asetilewa) |
Ko Aroko onileta si ore re nipa bi ile iwe re se ri. |
Read Also: JSS3 French Mock Examination Question- 3rd Term
Day 2
(Ọjọ Keji) |
14th March 2024 | 8th period |
Topic (Akọle) |
Aroko | |
Learning Objectives
(Erongba Idanilẹkọọ) |
Lopin idanilekoo awon akekoo gbodo le:
|
|
Key Vocabulary Words
(Ede Iperi) |
|
|
Previous Knowledge (Imọ Atẹyinwa) |
Awon akekoo ti ni imo nipa Aroso ati Aroko | |
Content
Akoonu Iṣẹ) |
Oriki Aroko ati igbese Aroko kiko Orisii Aroko ti o wa |
|
Strategies/ Activities
(Agbekalẹ) |
Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo. Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo. Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. |
|
Classwork
(Iṣẹ ṣiṣe) |
Ko igbese Arokọ Onileta | |
Conclusion (Igunlẹ) |
Olukọ salaye Ẹkọ lori arokọ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati jiroro lori akọle ti o le ba orisii Arokọ mu. | |
Assignment
(Ise Amurele/ Asetilewa) |
Kọ Arokọ Aṣapejuwe lori ILE ẸKỌ rẹ | |
Weekly quiz | ||
HODs. Comments and Endorsement |
AROKỌ
KINI AROKỌ?
Aroko ni ohun ti a ro lokan lori koko oro kan ti a si ko sile.
IGBESẸ AROKỌ KIKỌ
- Akole: akole ni ori oro ti a fe ko aroko le.
Bi apeere: Ounje ti mo feran julo
- Ilapa Ero: iwonyii ni awon koko kekeke ti alaroko ko jo lati fi gbe aroko re kale, ki aroko naa le e wa ni sise-n-tele. Sise Ilapa Ero ni lati dena gbigbe ohun ibere si ipari tabi ohun ipari si aarin.
- Ifaara: ohun ni ibere aroko. O gbodo dun, ki o gbe onkawe lokan soke, ki o si toka si akole.
- Ipin Afo: ipin afo ni ipin ti koko ero kookan wa. Leta nla ni a fi n bere ipin afo, ti a o si fi ami koma (,) ati ami idanuduro (.) sibi ti o ba ye.
- Koko Oro Inu Aroko: koko oro taka si isele inu aroko. Eran die egungun die ni isaasun obe fi n kun. Oro awada, oro efe to pa ni lerin gbodo han ninu aroko wa. Aroko wa ko gbodo gbe hau-hau.
- Igunle/Ikadii/Asokagba: ikadii aroko gbodo mo niwon, ki o dun, ki o si fi ero inu eni han.
ORISII AROKỌ
- Aroko Onileta
- Aroko Alalaye
- Aroko Asapejuwe
- Aroko Oniroyin
- Aroko Asotan
- Aroko Alariyanjiyan
- Aroko Ajemo-isipaya
LESSON CONTENT FORMAT
- Content should be on MS Word
- Font style (Comis Sans MS)
- Font Size (12)
Day 1
- State your objectives
- Copy and paste your full lesson note
Day 2
- State your objectives
- Copy and paste your full lesson note
Day 3
- State your objectives
- Copy and paste your full lesson note